ERIN WO, AJANAKU SUN BI OKE, BABA OLOYE AYO OLAYINKA, ORISAPETU TI ULU IPETU-IJESHA TI LO!
ERIN WO, AJANAKU SUN BI OKE, BABA OLOYE AYO OLAYINKA, ORISAPETU TI ULU IPETU-IJESHA TI LO!
Ka a to r’erin o di ugbo, ka a to ri efon o di odan!
Eri wo, ajanaku sun bi oke, Baba Oloye Orisapetu ti ulu Ipetu-Ijesha Baba Ayo Olayinka ti lo! O di arinnako o di oju ala!
Paga, oni lila, oloye agba, baba rere lo ni ulu Ipetu-Ijesha. A ku aseyinde baba rere o gbogbo omo ulu Ipetu-Ijesha lule, loko; odun a jinna sira rinhan o lagbara Olorun Eledumare.
Emi Ojogbon Andrew Ifemidayo Omo Akinmoladun ni oruko gbogbo omo bibi ulu Ipetu-Ijesha lule loko ki Kabiyesi Omowe ati Amofin Oba Samsoni Adeleke Agunbiade Oke III, Ajalaye ti ulu Ipetu-Ijesha, oloye ulu, borokinnin, gbogbo omo bibi ulu, ati alejo ulu Ipetu-Ijesha wi pe a ku aseyinde baba ria ko papo da.
Ni agbara Olohun Olodumore, Olohun a te baba si afefe rere, eyin rihan a da a. Olohun a wa pelu omo, ebi, ile, ati ona ki i baba fi sile lo.
Sun re o baba rere olufe gbogbo oniyan.
*Emi ni;*
*Ojogbon Andrew Ifemidayo omo Akinmoladun.*
*Ojo keji osu keje, odun 2025.*
TRENDING SONGS










Share this post with your friends on